7️⃣ Números

Español

Yoruba

  • cero
  • --
  • uno
  • kan • (contando) oókan • (un libro) ìwé kan
  • dos (v.tb.'los dos')
  • méjì • (contando) eéjì • (dos perros) ajá méjì • (dos casas) ilé méjì • [nums -190 no múltiplos de 10 siguen al n]
  • tres
  • mẹ́ta • (contando) ẹẹ́ta • (tres perros) ajá mẹ́ta
  • cuatro
  • mẹ́rin • (contando) ẹẹ́rin • (cuatro niños) ọmọ mẹ́rin
  • cinco
  • márùnún • (contando) aárùnún • (cinco bolígrafos) pẹ́ẹ̀nì márùnún
  • seis
  • (contando) ẹẹ́fà • (seis años (de edad)) ọdún mẹ́fà
  • siete
  • (contando) eéje
  • ocho
  • (contando) ẹẹ́jọ • (ocho perros) ajá mẹ́jọ
  • nueve
  • (contando) ẹẹ́sànán
  • diez
  • (contando) ẹẹ́wàá
  • once
  • (contando) oókànlá
  • doce
  • (contando) eéjìlá
  • trece
  • (contando) ẹétàlá
  • catorce
  • (contando) ẹẹ́rìnlá
  • quince
  • (contando) aárùnúndínlógún
  • dieciséis
  • (contando) ẹẹ́rìndínlógún
  • diecisiete
  • (contando) ẹẹ́tàdínlógún
  • dieciocho
  • (contando) eéjìdínlógún • (dieciocho años) ọdún méjìdínlógún
  • diecinueve
  • (contando) oókàndínlógún
  • veinte (incluye tb ejs 21-29)
  • ogún, ogun • (21) oókànlelógún • (22) eéjìlélógún • (23) ẹẹ́tàlélógún • (24) ẹẹ́rìnlélógún • (25) aárùndínló9gbò9n • (26) ẹẹ́rìndínlọ́gbọ̀n • (27) ẹẹ́tàdìnlọ́gbọ̀n • (28) eéjìdínlọ́gbọ̀n • (29) oókàndínlọ́gbọ̀n • (20 perros) ogún ajá • (22 perros) ajá méjìlélógún [v.'dos']
  • treinta (incluye tb ejs 31-39)
  • ọgbọ̀n
  • cuarenta
  • ogójì
  • cincuenta
  • àádọ́ta
  • sesenta
  • ọgọ́ta
  • setenta
  • àádọ́rin
  • ochenta
  • ọgọ́rin
  • noventa
  • àádọ́rùnún
  • cien
  • ọgọ́rùnún
  • mil (tb: miles)
  • ẹgbẹ̀rún • (6000 nairas al mes) ẹgbẹ̀rún mẹ́fà Náírà (ni fún oṣù kan / l'óṣù) • (5000) ẹgbẹ̀rún márùnún
  • millón
  • --