(prep) lẹ́hìn • (después del trabajo) lẹ́hìn iṣẹ • (descansamos (PS) después de clase) a simi lẹ́hìn kíláàsí • (conj) lẹ́hìn tí (después de terminar el trabajo, me dormí) lẹ́hìn tí mo parí iṣẹ, mo sùn • (después de dormir, nos sentimos mejor) lẹ́hìn tí a sùn, ara wa yá • (si implica condición) lẹ̀hìn tí… bá • (iremos al cine después de descansar) a máa lọ sí ilé sinimá lẹhìn tí a bá simi • (¿qué harás después de terminar los estudios?) kí ni o máa ṣe lẹ́hìn tí o bá parí ẹ̀kọ́ rẹ? • (Bib: ~~ estas cosas) lẹ́yìn nn`kan wọ̀nyí