nígbà wo? • (¿cuándo comió Kunle?) nígbà wo ni Kúnlé jẹun? • (¿cuándo vas a comer?) nígbà wo ni o máa jẹun?
cuánto
(~ es?) eélòó ni? • (¿cuánto es la mesa?) eélòó ni tábìlì? • (~ son tus zapatos?) eélòó ni bàtà rẹ? (mil nairas) ẹgbẹ̀run Náírà ni • (por ~ compró Tunji su coche?) eélòó ni Túnjí ra ọkọ̀ rẹ̀? • (en preg indirecta) oye tí • (no sé por cuánto Tunji compró su coche) n kò mọ oye tí Túnjí ra ọkọ̀ rẹ̀ • (no sé cuánto cuesta esta tela) n kò mọ oye tí aṣọ yìí jẹ́
cuántos
mélòó • (¿cuántos libros tiene Kunle?) ìwé mélòó ni Kúnlé ní? (tiene uno: Kúnlé ní ìwé kan) • (v.'vez')
cómo
báwo • (¿cómo está papá?) bàbá n´kọ́?
de dónde
(~~ eres?) ọmọ ìlú ibo ni ẹ́? (soy de Nigeria: ọmọ ìlú Nàìjíríyà ni mi)
de quién
--
dónde
dà?, níbo (ni ... wà?) • (¿dónde está tu hermano?) ẹ̀gbọ́n ẹ dà? • (¿dónde está él?) níbo ni ó wà? • (¿dónde está Kunle?) níbo ni Kúnlé wà? • (~ está...?) n´kọ́?
por qué
kí l'ó dé _? • (¿por qué/qué ocurrió?) kí l'ó dé? • (¿por qué estás haciendo ruido?) kí l'ó dé tí o ń pariwo?
quién
ta • (¿quién es la madre de Kunle?) ta ni màmá Kúnlé?
qué (pron interr)
kí • ('what?') kí ni? • (¿qué dijiste?) kí ni o sọ? • (¿qué comiste ayer?) kí l'o jẹ lánàá? • (¿qué quieres?) kí l'o fẹ́? • (¿qué te gusta hacer?) kí ni o fẹ́ràn láti ṣe? • (¿qué quieres hacer?) kí ni o fẹ́ ṣé?
qué (adj interr)
_ wo • (¿qué idioma hablas?) èdè wo l'o gbọ́? • (Colloq) _ wo ni • (¿qué casa compraste?) ilé wo ni o rà? • (¿qué libro está leyendo Kemi?) ìwé wo ni Kẹ́mi ń kà? • (¿qué coche compraste?) ilé wo ni o rà? •